Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà Ń Wá Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lu Tọ́kì Àtí South Korea

0 178

Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin Nàìjíríà ń wá i ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú Tọki ati South Korea, ní ẹ̀ka ètò ilé-ìgbìmọ̀, ètò-ọrọ̀ ajé àti ìmọ̀-ẹ̀rọ.

Aarẹ ile igbimọ aṣofin Ahmad Lawan, lo sisọ loju egun ni Ọjọ Ọjọrú lẹyin ijiroro pẹlu awon asoju orilẹ-ede Tọki, Hidayet Bayraktar ati South Korea, Kim Young-Chae ti o ṣe abẹwo si ni ọfiisi rẹ.

A o ranti pe Aare orile-ede Turkey lo se abewo si Naijiria ni osu to koja lasiko ti awon orile-ede mejeeji fowo si adehun kan.

 

Tolulope Akinseye

Leave A Reply

Your email address will not be published.