Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Àpapọ̀ Bu Ọwọ́ Lu Owó Tó Lé Ní Bilioni Naira Kan Fún Ẹ̀ka Òfúrufú

0 124

Ìgbìmọ̀ Aláse Àpapọ̀ ti fọwọ́ sí àdéhùn kan tí ó jẹ́ N1.4 bilion fún ríra àwọn ohun èlò ní pápá ọkọ̀ òfúrufú Nnamdi Azikiwe ní Abuja, olú-ìlú Nàìjíríà.

Minisita fun eto ọkọ ofurufu, Hadi Sirika lo ṣalaye eyi ni ọjọ Abamẹta fun Awọn oniroyin Ile ijọba ni ipari ipade minisita ti Aare Muhammadu Buhari ṣe olori.

O sọ pe erọ naa yoo gba imojuto gbogbo awọn irin oju-ofurufu laaye.

 

Tolulopẹ Akinṣẹyẹ

Leave A Reply

Your email address will not be published.