Take a fresh look at your lifestyle.

Asòfin Kan Ró Àwọn Ará Ìlú Rẹ̀ Tó Lé Ní Ọgọrun Lágbára Pẹ̀lú Ètò Ìkọ́sẹ́mọsẹ́

64

Aṣòfin kan tó ń ṣojú agbègbè kan ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi, Sẹnetọ Obinna Ogba, pẹ̀lu àjọṣepọ̀ ilé-isẹ́ tó ń rí sí ètò ìdàgbàsókè, ti kọ́ àwọn obìnrin àti àwọn ọ̀dọ́ Ebonyi tí ó jẹ́ aláìníṣẹ́ tí ó lé ní ọgọrun lẹ́ẹ̀kọ́ lórí ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ àti ètò iṣẹ́.

Idanilekọ naa waye ni ile itura Salt Lake, ni ilu Abakaliki.

Nigba ti o n soro lakoko idanilẹkọ naa, Sẹnetọ Ogba rọ awọn olukopa lati ma fọwọ yẹpẹrẹ mu idanilẹkọ naa ati pe ki wọn lo awọn ipese owo ti o tẹle idanilẹkọ naa daradara.

O tun  salaye pe pataki ẹkọ naa ni  lati din ainisẹ ku laarin awon ara ilu naa.

 

Tolulope Akinseye

Leave A Reply

Your email address will not be published.