Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ Mú isẹ́- Ìwáàdí Lọ́-kùn-kún-dùn

0 88

Igbákejì ààrẹ  orilẹ ede Naijria, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Osinbajo ti gba àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga níyànjú láti máa fọwọ́ yẹpẹrẹ mú isẹ́-ìwáàdí nítorí pé, èyí ṣe pàtàkì fún ìmúgbòòrò fun awọn to ba wa lati ilẹ̀ okeeere lati wa se isẹ́ iwadii lorilẹ ede Naijria.

Agbẹnusọ fun Igbakeji Aarẹ, Laolu Akande lo sọro yii  ninu ikede kan pe Ọjọgbọn Osinbajo sọ eyi ni Ọjọ Aje nigba ti o gba awọn aṣoju kan lati Ile-ẹkọ Fafiti  ipinlẹ Eko, (UNILAG Alumni Association), ti aarẹ ẹgbẹ naa jẹ , Dokita John Momoh .

Ọjọgbọn Osibanjo yana-na re pe, o ye ki ipese awọn ohun elo fun ṣiṣe iwadii wa lọpọ janturu lorilẹ ede Naijria.

Leave A Reply

Your email address will not be published.