Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Amòye Ìsàkóso Àjálù Pè Fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Àgbáyé

52

Àwọn minisita àti olórí ìgbìmọ̀ tó ń rí sí ètò àjálù lágbàyé ti ké gbàjarì sí àwọn olórí ilẹ̀ Afrika láti  má fọ́woọ́ yẹpẹrẹ mú ètò àjalù ní gbogbo ọ̀nà, ní ilẹ̀ Afrika.

Eyi waye ni ipade lori eto ajalu  ti o waye ni Nairobi, orilẹ-ede Kenya.

Ọgbẹni Mami Mizutori,  lo sọrọ  nibi ipade naa, o wa fi idi rẹ mulẹ pe, ìfọwọ́sowọ́pọ̀ laarin awọn adari Afrika, ijafafa ati eto ti o ni itumọ ni awon nnkan ti o nilo lati koju oro ajalu.

Leave A Reply

Your email address will not be published.