Take a fresh look at your lifestyle.

Atamátàsé Victor Osimhen Ti Farapa

47

Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríá àti agbábọ́ọ̀lù Napoli Victor Osimhen ti ní ìfarapa lẹ́yìn ìkọlù tí wọ́n ní pẹ̀lú ikọ̀ Inter Milan.
Oju osi ati eegun ẹrẹkẹ rẹ lo fi pa nibi idije naa, nigba ti ikọ Inter Milan fiya jẹ wọn pẹlu ami ayo 3-2.
Ikọ Napoli ko ti sọ ọjọ pato ti Osimhen yoo pada sori pápá, amo o se-e-se ki o to oṣu kan ti yoo fi wa labẹ itoju.

 

Tolulope Akinseye

Leave A Reply

Your email address will not be published.