Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn ènìyàn mẹ́tàdín-lọ́gọ́ta míràn tún ti ní ààrùn covid

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

41

Àwọn ènìyàn mẹ́tàdín-lọ́gọ́ta míràn ló tún ti kó ààrùn covid jákèjádò orílẹ̀-èdè báyìí.

Ile-iṣẹ to n mojuto ajakalẹ aarun lo kede rẹ lori bo ṣe n lọ.Gẹgẹ bii ile-iṣẹ ọhun,awọn eniyan wọnyi jẹyọ ni ipinlẹ mẹwa lorilẹ-ede.

Ipinlẹ Eko ( ọgbọn), Enugu-(mẹsan ), Rivers-(meje ), Kaduna-(mẹta), Ọṣun-(meta), Abia-(ẹyọkan), Bauchi (ẹyọkan), Kano-(ẹyọkan), Ogun-ẹyọkan), Plateau-(ẹyọkan).

Lọwọlọwọ bayii awọn eniyan ẹgbàájì- le- ni- ọ̀kẹ́- mẹ̀wá- abo- o- din-  loókànlá, ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin- le- ni- ọ̀kẹ́ mẹ̀wá- o- din- ni- èjì- le-  lọ́rin ti gba iwosan, ti ẹ̀rin-din-ni-ojì- din-  lẹgbẹ́ẹ́ẹdógún eniyan si ti jẹpe oluwa ni ipinlẹ mẹrindin-logoji ati olu-ilu.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.