Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19: Àwọn ènìyàn márùndínaláàdọ́ta míràn tún ti ní Corona

0 139

Àwọn ènìyàn márùndínaláàdọ́ta (45) míràn tún ti ní arun COVID-19  ti a mọ si COVID-19.

Ajọ to n mojutọ ajakalẹ arun lorilẹ ede Naijiria lo kede rẹ lori ẹrọ ayelujara lọjọ Abamẹta.

NCDC  tẹsiwaju pé ipinlẹ  mẹfa ni awọn eniyan to ni aarun COVID-19 ọhun ti jẹyọ .Awọn ipinlẹ ọhun ni: “Anambra-méjìdínlógún (18), FCT- márùndínlógún (15), Lagos- mẹ́sàn án (9), Bauchi-ọ̀kan (1), Kano-ọ̀kan(1), Rivers-( ọ̀kan)-1

Ni bayii iye awọn eniyan to ti ni aarun COVID-19 ti jẹ́ ẹgbàájì-lé-ní-ọ̀kẹ́-mẹ́ẁá-àbọ̀-dín-méjìlá-dín-ọrín (213,532) nigba ti awọn eniyan to ti gba iwosan ti jẹ́ ẹgbàáta-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀wá-le ni-eérinlá-din -ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta (206,486) awọn eniyan ẹ̀ta-din-ni-ojì din ni  ẹgbẹ́ẹ́ẹdógún (2,973) ti padanu ẹmi wọn.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.