Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ń darí àpèjọ lórí ayélujára

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 216

Ìpàdé  Ìgbìmọ̀ Aláse àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń tẹ̀síwájú ní Yàrá Àpèjọ  Ìyáàfin àkọ́kọ́,ní ilé-iṣẹ́ ààrẹ,ní Víllà, Àbújá.

Aarẹ Muhammadu Buhari ni o n dari apejọ ọhun,eyi ti o bẹrẹ ni deede agogo mẹwa owurọ.

Akọwe fun ijọba apapọ, Boss Mustapha; ọga agba fun awọn Oṣiṣẹe  Aarẹ, ọjọgbọn Ibrahim Gambari; Oludamọran Aabo fun Orilẹ-ede, ajagun Babagana Monguno; ati Akọwe Alailowaya, Ile-igbimọ Ipinlẹ, Umar Tijani;  wa nijoko nibi ipade naa.

Awọn minisita to tun wa nibi ipade naa ni, Adajọ agba ati Minisita fun eto idajo, Abubakar Malami;ọrọ  Inu orilẹ-ede, Rauf Aregbesola; Isuna, Inawo ati Eto Orilẹ-ede, Zainab Ahmed; Iṣẹ ati Ile, Babatunde Fashọla; ati Minisita fun eto ẹkọ, Chukwuemeka Nwajiuba.

Awọn alaye nigbamii.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button