Àwọn ènìyàn márùn-dín-lọ́gọ́sàn án míràn tún ti ní ààrùn covid
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó àjàkálẹ̀ ààrù ní orílẹ̀-èdè tún ti kéde pé ènìyàn márùn-dín-lọ́gọ́sàn àn míràn tún ti ní ààrùn covid.
Awọn eniyan marundin-lọgọsan yii jẹyọ lati ipinlẹ mọkanla-Lagos (mẹrinle-lọgbọn), Rivers (mẹẹdogun ), Gombe (mẹtala), Kano (mẹwa), Plateau (mẹjọ), Katsina (mẹfa), Bauchi (marun), Delta (marun), Benue (mẹrin),Nasarawa (meji).
The 175 new cases consist of records from 11 states with Lagos (34), Rivers (15), Gombe (13), Kano (10), Plateau (8), Katsina (6), Bauchi (5), Delta (5), Benue (4) and Nasarawa (2).
Lọwọlọwọ bayii,eniyan ẹgbàárin- le- ni- ọ̀kẹ́- mẹ̀wá- o- le- ni- èje- din- lọ ọgọ́jọ lo ti ni aarun naa,eniyan marundin-nigba ẹgbẹrun-le- lẹ̀rin-din-ni-ojì le ni ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́rún ti gba iwosan, ti ẹ̀rin-le-ni-ojì –din- ni -ẹgbẹ́ẹ̀rinlá eniyan si ti jẹpe oluwa.
Leave a Reply