Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn mẹ́fà pàdánù ẹ̀mí wọn nípasẹ̀ ìja ológun ti orílẹ̀-èdè Burkina Faso

Ademọla Adepọju

69

Ọ̀kan lára àwọn ọmọ ogun sọpé àwọn ènìyàn méje ni ó farapa níbi òpópónà tí wọ́n ń gbà sin àwọn ọkọ̀-epo níbi tí wọ́n ti pààlà pọ̀ mọ́ orílẹ̀-èdè Niger.

Ni ọdun meji sẹyin, awọn eniyan ọ̀kandinlogójì ni wọn pa nigbati awọn ọkọ ti wọn wa lori opopona kan na dojukọ ara wọn, ti isẹlẹ na si sokun fa ti ti awọn ile-isẹ kọkan pa fun bi ọdun kan.

Lati ọdun 2015, awọn ikọlu orilẹ-ed nipasẹ ẹgbẹ ti o sopọ mọ egbẹ ipinlẹ Islam ati Al-Qaeda ti sokun fa iku aimoyẹ awọn eniyan, o si ti fi kikan le aimoye awọn eniyan kuro ni ile wọn.

 

 

 

 

 

Damola ati kehinde

Leave A Reply

Your email address will not be published.