Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí ń darí àpèjọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

153

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ń  darí ìpàdé  Ìgbìmọ̀ Alásẹ lórí ayélujára ní yàrá àpèjọ ti ọ́fíísì Ìyáàfin Àkọ̀kọ̀, Ilé ìlú, Àbújá.

Igbakeji Aarẹ Yẹmi Osinbajo, Akowe fun ijọba apapọ, Boss Mustapha ati ọga agba fun awọn Oṣiṣẹẹ Aarẹ, Ọjọgbọn Ibrahim Gambari wa lara awọn ti o wa nijoko nibi ipade  naa, eyiti o bẹrẹ ni agogo mẹsan owurọ.

Bakannaa, minisita fun eto Ibaraẹnisọrọ ati ọrọ-Aje ayelujara, Isa Pantami, Ofurufu, Hadi Sirika,Minisita fun Idajọ, Abubakar Malami; ati iṣẹ, Dokita Chris Ngige wa nibẹ.

Awọn yooku ni  minisita ti Agbara, Abubakar Aliyu, Awọn orisun Omi, Suleiman Adamu ati ti Ipinle, Isuna ati Eto  Orilẹ -ede Clement Agba.

Olori  awọn oṣiṣẹ ijọba apapọ, Folashade Yemi-Esan ati awọn minisita miiran n kopa  lati awọn ọfiisi wọn  kaakiri ni ilu Abuja.

Awọn alaye Nigbamii …….

 

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.