Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí ń darí àpèjọ ìgbìmò aláṣẹ àpapọ̀

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

145

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ń darí àpèjọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀ lórí ayélujára ní yàrá ìgbàlejò ìyá àfin àkọ́kọ́,ní ọ́físìì olú-ìlú,Àbújá.

Igbakeji Aarẹ Yemi Osinbajo, Akowe fun ijọba apapọ, Boss Mustapha ati ọga agba fun awọn Oṣiṣẹẹ  Aarẹ, Ọjọgbọn Ibrahim Gambari wa lara awọn ti o wa nijoko nibi ipade naa, eyiti o bẹrẹ ni deede agogo mẹsan owurọ.

Bakan naa ni  Minisita fun Isuna,inawo ati Eto Orilẹ -ede, Zainab Ahmed; Agbejoro Agba ati Minisita fun Idajo, Abubakar Malami; iṣẹ ati Ibugbe, Babtunde Fashola ati ti Ibaraẹnisọrọ ati ọrọ aje ori ayelujara, Dokita Isa Pantami.

Awọn miran to tun pẹlu ni,  minisita  Ọkọ ofurufu, Hadi Sirika;idagbasoke irin ati alumọni inu ilẹ, Olamilekan Adegbite, Omoniyan, Isakoso Ajalu ati Idagbasoke Awujọ ati  ti Ọdọ ati Idagbasoke Ere idaraya, Sunday Dare.

Olori awọn oṣiṣẹ ijọba apapọ, Folashade Yemi-Esan ati awọn minisita miiran n kopa  lati awọn ọfiisi wọn ni Abuja lori ayelujara.

Aarẹ Buhari kọkọ ṣe ifilọlẹ Igbimọ  Alaṣẹ Idoko -owo Ijọba ti Naijiria, ki ipade to bẹrẹ .

Awọn alaye Nigbamii …….

Leave A Reply

Your email address will not be published.