Take a fresh look at your lifestyle.

NIDCOM gbóríyìn fún aṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àkọ́kọ́ ní Ọsirélíà

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

147

Àjọ tó ń ṣàkóso ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ Nàìjíríà tó ń gbé lókè òkun,NIDCOM,ti kí aṣojú rẹ̀ àkọ́kọ́ ní Ọsirélíà kú oríi re.

Alaga  Igbimọ naa, Abike Dabiri-erewa ninu ifiranṣẹ ikini ku oriire  kan, ki Abiola Akinbiyi lori bi wọn ṣe    ṣẹṣẹ  yan,  gẹgẹ bi Komisọna Aṣoju Agbegbe Naijiria akọkọ ti Igbimọ Oniruuru Ilu Victoria ni Australia.

Gẹgẹbi aṣoju NIDCOM, yiyan Akinbiyi  fihan gbangba pe o ni oye oludari  ati ifẹ si awọn obinrin ati ironilagbara ọdọ.

O rọ  pe, ki o ma ṣe yinupada lori aanu to n ṣe fun awọn ọmọniyan ,bẹẹni ki o si doju kọ  igbiyanju lati ṣaṣeyọri lọpọlọpọ lori gbigbọ tọmọniyan.

Minisita fun Awọn Iṣẹ Aṣa Oniruuru, Hon. Ros Spence, Prime Minisita ti Victoria, ti Ẹgbẹ Oṣiṣẹ Ọstrelia ni o kede yiyan Akinbiyi pẹlu awọn miran.

Akinbiyi, jẹ adari agbegbe ati alagbawi,  ogbontarigi olutaja ti o si tun jẹ  Obinrin ati awokọṣe fun awọn Ọdọ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.