Take a fresh look at your lifestyle.

Ìmọ̀ ayélujára le ṣàlékún Ìdàgbàsókè ìbáṣepọ̀ ọrọ̀ -ajé-NCC

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 226

Igbákejì  Aláṣẹ alága àti  Aláṣẹ àgbà  Ìgbìmọ̀ ilé-iṣẹ́ tó ń rísí Ìbáraẹnìsọ̀rọ̀  ní orílẹ̀-èdè Nàìjíŕià (NCC), Ọ̀jọ̀gbọ́n Umar Danbatta, sọ pé,ìmọ̀ ayélujára yóò ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ará ìlú láti ní ìfọwọ́sowọ́pọ̀ tó múná dóko nípa pípèsè akoonu lórí ayélujára  àti láti jẹ́ olùṣẹ́gun ìmọ̀ tuntun láàrin ìlọ́lùpò ètò-ọrọ̀-ajé wọn.

Nibi ti o ti n sọ ọrọ rẹ ,eyi to jẹ alakọkọ rẹ ọlọdọọdun ni Bichi Emirate,ti akọle rẹ jẹ, , “imọ ayelujara, igbesẹ to tọ fun igberu awujọ ati ọrọ -aje” ni Bichi,ipinlẹ Kano,arewa iwọ-oorun, orilẹ-ede Naijiria,Danbatta rọ awọn oṣere abala gbogbogboo ati aladani lati tẹwọgba eto naa.

Alaṣẹ NCC pe akiyesi si pe, imọ  ayelujara pese afọkantan ti awọn ara ilu kọọkan nilo, lati lo akoonu ati awọn irinṣẹ ayelujara.

O sọ pe, ọkan ninu awọn idi imulo mẹta rẹ lo da lori idagbasoke  eto -ọrọ aje orilẹ -ede Naijiria, nipasẹ atunṣe imọ -ẹrọ ayelujara amayedẹrun ati alekun afọwọsowọpọ  ti eka ẹrọ ibaraẹnisọrọ ati si  (GDP) orilẹ -ede.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button