Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19: Àwọn ènìyàn Naijiria mẹ̀rin-din-ni-ojì-din-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́rin tún ti ní àrùn Conona

87

Àwọn ènìyàn Naijiria mẹ̀rin-din-ni-ojì-din-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́rin tún ti ní àrùn Conona

Ajọ to n gbogun ti ajakalẹ arun lorilẹ ede Naijiria ,NCDC  ti kede pe àwọn ènìyàn  mẹ̀rin-din-ni-ojì-din-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́rin tún ti ní àrùn Conona  ni ipinlẹ mẹtadinlogun .Awọn ipinlẹ naa ni :- “Eko ,màrún-din-ni-ọ́ta-lelọ́ọ̀dúnrún (355), Rivers, mẹ̀ta-din-ni-àádọ́rùn (87), FCT, mejidinlogoji (38), Ogun, mẹtalelọgbọn (33) Akwa Ibom, mejilelọgbọn (32),Oyo,mejilelọgbọn (32), Edo, mejilelogun (22), Ekiti, ogún  (20), Kwara , mẹtadinlogun(17), Delta, mejila  (12), Bayelsa, mẹjo (8), Gombe , marun un (5) Kaduna mẹrin (4), Osun, mẹrin  (4), Enugu , meji(2) Nasarawa, meji (2), ati Plateau , ookan(1).”

Ni bayii , iye awọn eniyan to ti ni aarun COVID-19 jẹ ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀sán-o-le-ni eétalá-din-ni  -ọ́rin-le-nigba (185,267) , nigba ti awọn eniyan ti iye wọn jẹ ẹgbàárin-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-din-ni-ẹ̀ta-din-ni-ọ́rin (167,923), ti awọn eniyan ti iye wọn jẹ ẹ̀rin-le-ni-ojì-le-ni-ẹgbẹ́ọ̀kànlá(2244 ). si ti jẹ́ Ọlọrun nipe

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.