Take a fresh look at your lifestyle.

Mínísítà – ÒfinTuntun Ilé -iṣẹ́ Epo rọbi yóò Fa ojú Àwọn olùdókòwò mọ́ra

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

136

Mínísítà  Ìpínlè fún  epo rọbi lorilẹ ede Naijiria ,Timipre Sylva, sọ pé òfin tuntu ti ààrẹ orílẹ̀-èdè buwọ́lù yóò fa ojú àwọn olùdókòwò mọ́ra.

Minisita naa ṣalaye eyi, lakooko ti o n dahun awọn ibeere awọn akọroyin nipa ofin tuntun tii aarẹ fọsọsi ọhun niluu Abuja, ni ọjọ iṣẹgun.

Sylva sọ pe,aarẹ Muhammadu Buhari yoo yanana ọrọ lori ofin ọhun,eyi ti yoo ṣe iranlọwọ lati ṣe idagbasoke ẹka epo rọbi ati gaasi, ni ọjọ iṣẹgun.

O ṣe akiyesi pe,o yẹ ki a ṣọra bi a o ṣe maa diyele owo lori ati ṣeto iṣẹ ,nitori pe, ipa rẹ yoo han lara awọn agbegbe miran.

O sọ pe, bi owo oṣiṣẹ ba pọju ,eyi yoo dẹruba awọn oludokowo ni orilẹ-ede .

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.