Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí yan Ìgbìmọ̀ Olùdarí Fún Òfin Ilé -iṣẹ́ Epo rọ̀bì

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

137

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárì ti bẹ̀rẹ̀ ìmúse  Òfin Ilé -iṣẹ́ epo rọbi  tí o sẹsẹ fọwọ́ sí (PIA) nípa fífi oǹtẹ̀ lù  ìgbìmọ̀ olùdarí láti ṣe àbojútó ìlànà náà.

Minisita ti ipinlẹ fun epo rọbi lorilẹ ede Naijiria,Timipre Sylva ni yoo maa dari Igbimọ naa.

Awọn ọmọ ẹgbẹ ọhun naa  ni: Akowe agba  fun  Ile -iṣẹ  epo rọbi , Oludari ile-isẹ́, NNPC, oudari ile-isẹ́  FIRS, Aṣoju  Ile -iṣẹ  eto  Idajọ, Aṣoju  Ile -iṣẹ  eto  Isuna, Inawo ati Eto Orilẹ -ede, Oluranlọwọ Pataki fun aarẹ lori Adayeba Awọn orisun, Olufemi Lijadu gẹgẹ bi Oludamọran Ofin okeere,  ti Akọwe Alase, fun eto  idagbasoke ẹrọ epo rọbi. .

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.