Take a fresh look at your lifestyle.

ilé-isẹ́ NNPC yóò sètò ìránwọ́ fún ilé-isẹ́ NLNG lórílẹ̀ ède Naijiria

97
Alakoso ile isẹ to n samojuto epo rọbi lorilẹ ede Naijria ,National Petroleum Corporation (NNPC), Mallam Mele Kyari,  ti tẹpẹlẹmọ  ileri rẹ lati  tubọ maa seto iranwọ fun ile-isẹ to n samojuto afẹfẹ gaasi lorilẹ ede Naijria,Liquefied Natural Gas (NLNG) lati jẹ ki wọn lee wa ni ibamu pẹlu awọn akẹgbẹ wọn lorilẹ ede agbaye.
lasiko ti oludari ayẹyẹ ọhun,Nike Kolawole ti o sju alakoso ọhun,  n sọrọ nibi ipade apero nipa sise  eto aabo  fun ara ẹni ati ayika ti ọdun 2021 .
Leave A Reply

Your email address will not be published.