Ibrahim Mantu di olóògbé,ààrẹ Buhari sọfọ̀ ikú Igbákejì adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin tẹ́lẹ̀rí
Ademọla Adepọju
Aarẹ Muhammadu Buhari ti darapọmọ Gomina Ipinlẹ Plateau ati awọn ara ilu lati se ìdárò igbakeji aarẹ ile ìgbìmọ̀ asòfin àgbà tẹ́lẹ̀rí, Ibrahim Mantu láti ṣọ̀fọ̀ ikú olóṣèlú olókìkí naa.
Aare Buhari se idaro naa pelu awọn adari,awọn ọmọ Orilẹ-ede Naijiria , awọn ọrẹ ati awọn oloselu nipa iku Ibrahim Mantu , ti o fi gbogbo igbesi aye rẹ sin awọn eniyan rẹ.
Aarẹ gbadura pe ki Ọlọrun tẹ oloogbe naa si afẹ́fẹ́ ire
Damola ati Kehinde
Leave a Reply