Take a fresh look at your lifestyle.

E jẹ́ ká dìbò ká máa baà dá àwọn n tó bọ̀ dúró- UN àti AU

Ademọla Adepọju

84

Àjọ àgbáyé UN àti ẹgbẹ́ Orílẹ̀-èdè Afirika AU ti rọ Orílẹ̀-èdè Somalia láti se ìdìbò Orílẹ̀-èdè wọn ti wọn ti  dá dúró télè ní Osù kẹwa, Ọdún yìí, pé kí wọ́n máa se  bìkítà bí àwọn alakatakiti ẹlẹsin  Musulumi. se n dún ikooko mọ wọn..

Ajọ Agbaye to n mojuto ọrọ oselu  ni orilẹ-ede ti se akọsilẹ awọn ara ilu  ti iye wọn jẹ ọ̀kan-le-ni-okòó-lelọ́ọ̀dúnrún (321) ni wọn sọ pe wọn  ti wọn padanu ẹmi wọn ni ọdun ti a wa yii, paapaa julọ ti pupọ  wọn jẹ ọmọ ẹgbẹ Al-Shabab

O ti to osu meji bayii ti wọn ti sun eto idio aarẹ ati ile igbimọ asofin siwaju  nipasẹ ede aiyede laarin ijọba ati awọn alatako.

 

 

 

Hamzat Damola

Leave A Reply

Your email address will not be published.