Take a fresh look at your lifestyle.

Ahmed Joda di olóògbé, ìpínlẹ̀ Adamawa sèdárò rẹ̀

100

Gomina ipinlẹ Adamawa, Ahmadu Umaru Fintiri  ti sapejuwe iku  akinkanju ati olufọkansin , akọwe agba ijọba apapọ ti o jẹ ọmọ ipinlẹ  Adamawa, Ahmed Joda , ti o di oloogbe ni Ẹti ,ọjọ kẹtala, osu kẹjọ, ọdun yii.

O tẹsiwaju pe  Joda  fẹran awọn eniyan  ati orilẹ ede rẹ̀ .O daju pe awọn osisẹ rẹ, oloselu , awọn akọroyin yoo sàfẹ́rí isẹ́ ribi-ribi  ti o ti se fun idagbasoke orilẹ ede Naijiria , paapaa julọ ni  ipinlẹ Adamawa ati ni agbegbe rẹ.

“Mo ba ara mi , ẹbi mi, ijọba ati awọn ọmọ ipinlẹ  Adamawa kẹdun , Mo si tun ba ẹbi oloogbe Alhaji Ahmed Joda. kẹdun pẹlu.Bi ẹ se n sedro oloogbe naa, ẹ tun maa dupẹ lowọ Ọlọrun fun isẹ́ rere atiigbe ayé alaafia ti oloogbe naa gbé ki o to jade kuro laye.

Gomina wa gbadura e ki Ọlọrun tẹ oloogbe naa si afẹfẹ ire.

Leave A Reply

Your email address will not be published.