Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbìmọ̀ Ilé-aṣòfin rọ Àwọn Onísègùn Olùgbe Láti fòpin sí ìyanṣẹ́lódì

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

115

Ìpaldé ìdúnàádúrà ọlọ́jọ́ méjì tí ilé-ìgbìmọ̀ aṣofín fún Àwọn iṣẹ́ Ìlera ṣe pẹ̀lú ìpinnu láti fòpin sí ìdaṣẹ́sílè tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ oníṣègùn olùgbé jákèjádò orílẹ̀-èdè NARD,bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ ìṣẹ́gun,bọ́ sí pàbó.

Lẹhin ti o fẹrẹ to  wakati meje ti ipade naa ti bẹrẹ, aṣoju NARD to rọpo Alakoso rẹ, Dokita Okhuiahesuyi Uyilawa  bura pe awọn ko ni fopin si iyanṣẹlodi jakajado orilẹ-ede naa, ayafi ti wọn ba dahun si awọn ibeere mẹtadin-logun wọn .

Awọn ibeere ọhun ni – isanwo lẹsẹkẹsẹ  awọn  ekunwo owo-oṣu ati awọn ẹkunwo ti wọn fo  lati ọdun 2014 si ọdun 2016, eyiti o jẹ bilionu mẹtale-logun Naira; idaduro  Awọn Onisegun oṣiṣẹ fidihẹ, yiyọ kuro lẹsẹkẹsẹ  apinka ariyanjiyan lori yiyọ  Awọn oṣiṣẹ Ilera kuro ninu Eto Iṣẹ,ati gbigba awọn oniṣegun olugbe siṣẹ ile-iwosan gbogbogbo lakoko pajawiri.

Aṣoju ijọba ti o dari ikọ naa, Minisita  Ipinle fun Ilera, Sen. Olorunmimbe Mamora ti bura  lati tẹle ilana ti o yẹ fun eto -iṣe lori ijẹrisi awọn orukọ Awọn Onisegun Ibugbe ṣaaju isanwo N5.42 bilionu marun ati diẹ owo osu ati awọn owo sisan to dayato.

Aṣofin Mamora sọ siwaju pe, awọn alaṣẹ ilera le da ṣẹria to tọ fun  igbanisiṣẹ ti oṣiṣẹ iṣoogun laisi atẹle ilana to tọ, laibikita ipo pajawiri.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.