Take a fresh look at your lifestyle.

Akọrin olóhùn iyọ̀, Waje pàdánù bàbá rẹ̀

0 188

Ògbóntarìgì akọrin olóhùn iyọ̀, to jẹ́ ọmọ orilẹ ede Naijiria ,Waje ti  pàdánù bàbá rẹ̀.

Akọrin naa lo kede lori ikanni ẹrọ ayelujara  Instagram rẹ lọjọ Isẹgun ojọ kẹwaa, osu kẹjọ ,ọdún  2021 nípa iku baba rẹ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.