Take a fresh look at your lifestyle.

A ti mú àwọn oníṣòwò òògùn egbòogi olóró mẹ́tàlélógójì – NDLEA

60

Àjọ tó ń gbógun ti gbígbé àti mímu òògùn egboogi  olóró lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà,NDLEA ti mú àwọn oníṣòwò òògùn olóró mẹ́tàlélógójì ni ipinlẹ  Nasarawa, Benue ati Ondo.

Olùdarí ẹka to n mojuto iroyin ni Ilé-isẹ́ NDLEA ní Ìlú Abuja , ọgbẹniu  Femi Babafemi  lo sọrọ yii lasiko to n ba awọn akọroyin sọrọ niluu Abuja.

Alako ajọ  NDLEA, ajagunfẹyinti Mohammed Buba Marwa  ,, wa gbosuba fn ikọ ọmọ ogun rẹ to wa ni ipinlẹ Nasarawa, Ondo ati  Benue fun gudugidi meje , yaya mẹfa ti wọn n se lati gbogun ti awọn to n gbìn, tà, rà ati mu egbòogi àti òògùn oloro lorilẹ ede Naijiria.

o wa tun rọ wọn lati maa kaarẹ ninu igbiyanju wọn lati ri i pe wọn tubọ gbogun ti gbogbo awọn ọ̀bàyèjẹ wọnyi lorilẹ ede Naijiria.

 

 

 

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.