Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbẹ́jọ́ nípa Zuma bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹu lórí ẹ̀rọ ayélujára

Ademọla Adepọju

127

Aarẹ orilẹ ede South Africa tẹ́lẹ̀rí, Zuma, ti o jẹ́ ẹni ọdún mọ́kàndínlọgọrin, lo ti n fi  ẹ̀wọ̀n oṣù mẹ́ẹ̀dógún  gbára láti  oṣù tó kọjá.

lara ẹ̀sùn ti wọn fi kan Zuma ni awọn iwa ibajẹ ati  lilo iwa ipá ati awọn iwa ọdarna miran ,ni eyi ti ẹjọ́ naa waye nipa lilo awọn fidio ati lori ẹrọ ayelujara bo tilẹ jẹ pe awọn agbẹjọro jà fita-fita lori ọna ti ìgbẹ́jọ́ yii ṣe n waye pe , lilo ẹrọ ayelujara ati lilo fidio fun eto igbẹjọ ko bojumu ati pe o lodi si ilana òfin.

Ẹsun mẹrinlelogun ni wọn fi kan Zuma, lara rẹ ni ; gbigba ríbá, gbigba owó àbẹ̀tẹ́lẹ̀ ati awọn iwa ibajẹ miran.

 

KEHINDE ATI DAMOLA

Leave A Reply

Your email address will not be published.