Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì ààrẹ, Òsínbàjò ń darí ìgbìmọ̀ ìjọba àpapọ̀

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

160

Igbákejì ààrẹ orílẹ̀-èdè,ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò ń darí  ìgbìmọ̀ ijọba apapọ aláṣẹ lórí ayélujára,èyí tí ó bẹ̀rẹ̀ ní agogo mẹ́wàá òwúrọ̀ ní ọjọ́ọ́rú.

O jẹ ipade igbimọ  akọkọ lati igba ti aarẹ Muhammadu Buhari ti rin irin-ajo lọ si United Kingdom, lati kopa ninu Apejọ Ẹkọ Agbaye ati fun ayewo ara rẹ.

Ipade  Igbimọ ọjọbọ ọhun n waye  ni ọsẹ kẹta, lẹhin eyi ti o waye ni ọjọ kẹrinla Oṣu Keje, ọdun 2021, ṣaaju ayẹyẹ ọdun ileya.

Akọwe fun Ijọba  apapọ, Boss Mustapha; olori osise fun aarẹ, Ọjọgbọn Ibrahim Gambari, igbakeji ọga agba fun awọn oṣiṣẹ, Ade Ipaye; ati Akowe Pataki,fun Ile-iṣẹ si olu ilu , Tijani Umar, wa ni ijoko nibi  ipade naa.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.