Take a fresh look at your lifestyle.

Covid-19:Àwọn ènìyàn méje-lé-ní-irinwó míràn tún ti ní àrùn Corona lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà

0 249

Àjọ tó ń gbógun ti àjàkálẹ̀ àrùn lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà tún ti kéde pé àwọn ènìyàn méje-lé-ní-irinwó míràn tún ti ní àrùn Corona lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà.

Ni bayii iye awọn eniyan to ti ni arun COIVD-19 ti jẹ́ ẹgbàájì-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-abọ-le-ni màrúnún-din-ni -okòó-lelọ́ọ̀dúnrún  (174,315) , iye awọn eniyna to ti gba iwosan naa jẹ  ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-le-ni-màrún ún (165,005) , nigba ti awọn eniyan oókànlá-din-ni-ọ́ta-le-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá ( 2,149) si ti padanu ẹ̀mí wọn.

Awọn ipinlẹ mẹtadinlọgbọn ni arun yii ti jade, awọn ipinlẹ naa ni : Lagos, ọgọ́jọ (160), Akwa Ibom,màrún-din-lọgọ́rin (75), Ondo,ọ̀kan-le-ni-àádọ́ta (51), Abi, mẹtalọgbọn (33), Oyo, ookandinlọgbọn (29), Kaduna, mejidinlogun (18), Katsina, méje mẹ́fà (7), Gombe, mẹ́fà (6), Ogun,mẹ́fà (6), Ekiti , marun un (5), Delta, mẹrin (4), FCT, mẹrin  (4), Ebonyi, mẹ́ta (3), Edo, meji (2), Niger, meji (2), Bayelsa, ookan (1), ati Nasarawa, ookan (1)

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button