Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19:Àwọn ènìyàn mẹ́tà-dín-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta míràn tún tí ni Corona ní Nàíjíríà

50

Àjọ tó ń gbógun ti àjàkálẹ̀ àrùn lórílẹ̀ èdè Nàíjírí́à  ti kéde pé àwọn ènìyàn mẹ́tà-dín-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta (497)míràn tún tí ni Corona lórílẹ̀ èdè Nàíjírí́à báyìí.

Ipinlẹ mejidinlogun ni arun naa ti gbé jẹyọ awọn ipinlẹ ọhun ni – Lagos,mẹ̀sán-din-ni-okòó-le-nigba.(211), Akwa Ibom ,ọgọ́rin (80), Kwara,mẹ́tà-lé-ní-àádọ́rin (73), Osun, mọkandinlọgbọn (29), Oyo , mẹtadinlogun (17), Rivers,mẹtadinlogun (17), Cross River, mẹẹdogun (15), Edo, mẹrinla (14), Anambra,mesan an (9), Ogun, mẹ́jọ  (8), Ekiti, mẹ́fà  (6), Bayelsa, mẹrin (4), FCT, mẹ́rin(4), Plateau, mẹrin  (4), Bauchi ,mẹ́jì (2), Nasarawa , meji (2), Kaduna, ookan (1) àti Jigawa, ookan (1).

Ni bayii ,àpapọ̀  iye awọn eniyan to ti ni arun naa jẹ́,ẹgbàájì-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-̀aàbọ̀din-ni-mèjì-le-ni-àádọ́rùn (173,908)  , bakan naa, iye awọn ti wọn ti gba iwosan naa jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-din-ni-mẹ́fà (164,994) nigba ti iye awọn eniyan ti  o di oloogbe naa jẹ ,oókànlá-din-ni-ọ́ta-le-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá  (2149) .

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.