Take a fresh look at your lifestyle.

ògbóǹtarìgì òsèré orí sinimá,Rachel Oniga di olóògbé

148

Ògbóǹtarìgì òsèré orí sinimá,Nollywood, Rachel Oniga di olóògbé.

Rachel Oniga jẹ Ọlọ́run nipe  ní Ọ̀gbọ́njọ́ , ọjọ́ Ẹti  . Ọmọ  ọdún mẹrinlelọgọta (64) ni  oloogbe Rachel Oniga , ki o to jẹ Ọlọrun nipe lẹyin aisan ranpẹ.

A bí Rachel Oniga ni ọjọ kẹtalelogun ,osu karun un ọdun 1957 ní Ebutte Metra,niluu Eko  sugbọn , o jẹ ọmọ ile Eku , ni ipinlẹ Delta .

Eré ti akọle rẹ jẹ ‘Onome” lọdun 1966, lo sọ Rachel Oniga gẹgẹ bi  ogbontarigi osere sinima.

lara awọn ti Rachel Oniga  ti  ba se eré  ni  Wale Adenuga ,‘Super Story’. O tun lọwọ nibi eré ti wọn pe ni ‘Chief Daddy,’ ‘Royal Hibiscus Hotel’ ati ‘My Village People.’

Ọmọ mẹ́ta ati ọpọlọpọ ọmọ-ọmọ ni oloogbe fi silẹ láyé.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.