Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19: Ẹ̀yin ẹgbẹ́ òsèlú , ẹ́ máa tẹ̀lé ìlànà gbígbógun ti àrùn Corona

138

Ìgbìmọ̀ ijọba apapọ to n mojuto gbigbogun ti arun COVID-19  lorilẹ ede Naijria ti sèkìlọ̀ fun gbogbo ẹgbẹ oselu to wa lorilẹ ede Naijria lati maa tẹlẹ ilana aarun Corona.

Igbimọ sekilọ  yii nitori bi arun COVID -19 se n pọ si lorilẹ ede Naijiria  ni awọn ipinlẹ orilẹ ede yii.

Ìgbìmọ̀ ijọba apapọ to n mojuto gbigbogun ti arun COVID-19  lorilẹ ede Naijria wa sekilọ fun gbogbo awọn  ẹgbẹ́ oselu, ajọ ijọba apapọ to n mojuto eto idibo lorilẹ ede Naijria,ajọ   to n mojuto eto idibo ni ipinlẹ lati ma tẹle ilana ti wọn la silẹ lati gbogun ti arun COIVD-19 lorilẹ ede Naijiria.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.