Take a fresh look at your lifestyle.

Ìkọlù Àwọn ọlọ̀tẹ̀: Nàìjíríà, UK Ṣèlérí Ìdájọ́ òdodo Fún Gbogbogbòò

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

187

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí àti ọ̀gá àgbà Mínísítà Boris Johnson, ti Ìlú Gẹ̀ẹ́sì ní ọjọ́bọ̀, ṣe àtúnyẹ̀wò ìgbógunti  àwọn oríṣiríṣi ìwà jàgídíjàgan ní Nàìjíríà, àti pé ó tún gbà pé  wọ́n ní láti gba ìlànà òfin  láàyè láti ṣiṣẹ́ ní ọ̀nà  tirẹ̀.

Nibi ti wọn ti n  jiroro abalameji lori awọn ẹgbẹ ti Apejọ Ẹkọ Agbaye ni Ilu Lọndọnu, awọn adari mejeeji sọ pe, o ṣe pataki pe ilana idajọ n ṣiṣẹ laisi kikọlu, laibikita ẹniyowu ki o jẹ.

Aarẹ Buhari ṣe alaye fun ọga agba Minisita lori awọn pataki akanṣe orilẹ-ede Naijiria ati awọn igbiyanju ti wọn n ṣe, pẹlu awọn ipilẹṣẹ ti a ṣeto lati ṣaṣeyọri aabo ounjẹ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.