Take a fresh look at your lifestyle.

ikú dóró! Àgùnbánirọ̀ márùn ún pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ìjàm̀bá ọkọ̀ nílùú Àbújá

141

Aarẹ  Muhammadu Buhari ti fi ibanujẹ ọkàn  rẹ han si ikú awon agunbanirọ marun un ti wọn padanu ẹ̀mí wọn nibi ijamba ọkọ to waye loju ọna márosẹ̀ Abaji/Kwali  niluu , Abuja .

Ninu atẹjade kan ti aarẹ fi ransẹ si igbimọ  to n sakoso awọn agunbanirọ ati ile -isẹ to n samujoto awọn agunbanirọ ọhun  lati ba wọn kẹdun lori isẹlẹ buruku ọhun.

Aarẹ Buhari tun wa ba awọn ẹbi , ọrẹ ati  ojulumọ  kẹdun lori isẹlẹ naa, o tun wa tẹsiwaju pe orilẹ ede Naijria yoo tẹsiwaju lati maa fi adura ran wọn lọwọ lasiko ipenija yii.

Aarẹ wa tun fi adura ransẹ si awọn agunbanirọ yooku pẹ Ọlọrun a jẹ ki wọn se aseyọri, ti alákàn ń sepo.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.