Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19: Awọn eniyan méjìlá-din-ni-ọ́rin-le-nigba míràn tún ti ní àrùn corona

47

Àjọ to n gbogun ti ajakalẹ àrùn lorilẹ ede Naijria,the Nigerian Centre for Disease Control, NCDC,ti ní awọn eniyan  méjìlá-din-ni-ọ́rin-le-nigba míràn tún ti ní àrùn corona  bayii.

Ni bayii  iye awọn eniyan ti o ti ni  arun COVID-19 lorilẹ ede Naijiria ti jẹ́ ẹgbẹ́rún-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-aabọ-din-ni-màrún ( 170895) nigba ti awọn eniyan ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta-le-ni-ọ̀kẹ́-mẹ̀jọ-dín-ni-méjìlá ti gba ìwòsàn (164788) nigba ti awọn eniyan mẹ̀jọ-din-ni-ojì-le-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá (2132) ti padanu ẹ̀mí wọn.

Awọn ipinlẹ mẹsan an ni aarun naa ti jẹyọ , awọn ipinlẹ naa ni: Eko mèjì-le-ni-ọgọ́sán (182), Rivers mẹrinlelọgbọn (34), Ondo ,mẹrinlelogun (24), Oyo, mẹwaaa (10), Abia ,meje (7), Ogun, meje  (7), Ekiti (5) marun un , Delta (2) meji , ati Plateau(1) ọkan

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.