igbákejì ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, ọjọgbọn Yemi Osinbajo ti rọ àwọn adarí láti mọ́kànle nínú ìpọ́njú tàbí ìpèníjà tí wọ́n bá ń dojúkọ kí wọ́n leè jẹ́ àwọkọ́se rere fún àwọn ti wọ́n ń darí.
Osinbajo sọrọ yii lọjọ Ẹti nibi ayẹyẹ ọjọkarundinlọgbọn ti ile-ẹkọ ile-ijọ irapada ,the Redeemed Christian Church of God ,se, ni eyi ti wọn pe akọri rẹ ni : Bibori ipọnju .
Ninu atẹjade kan ti ile-isẹ igbakeji gbe jade , ni o ti salaye pe nigba ipọju ni a maa nilo awọn adari.
Leave a Reply