ÌJỌBA ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÌJÍRÍÀ KÉDE ỌJỌ̀ ÌSẸ́GUN ÀTI ỌJỌ́RÙ FÚN AYẸYẸ ỌDÚN ILÉYÁ
Ademọla Adepọju
Minista fún ètò abẹ́lé, Ogbeni Rauf Aregbesola, ti se ìkéde pé ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ti ya Ọjọ́ ìségun (Tuesday) àti ọjọ́rú (Wednesday) tí se osù keje, ọdún tí a wà yíí fún ọjọ́ ìsinmi láti fi se ayẹyẹ ọd́un mùsùlùmí tí a mọ̀ sí Eid-Al-Adha.
Aregbesola lo anfani naa lati ki gbogbo ọmọ musulumi ati awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria nile, loko ati loke okun fun ayẹyẹ ọdun naa.
O si tun rọ awọn ọmọ orilẹ-ede lati tẹle ilana aarun Corona (Covid-19) nipasẹ bibo imu, fifọwọ ati fifi alafo silẹ laarin ara wọn.
Damola and Kehinde