Take a fresh look at your lifestyle.

ICPC- àwọn oníṣẹ́ ọlọgbọ́n gbọ́dọ̀ kópa nínú ìwà ìṣẹ̀tọ́ lórílẹ́-èdè

Fauziat Eyitayọ Oyetunji

0 286

Ìwà-ìṣẹ̀tọ́ ní Orílẹ̀-èdè àti ìlànà ìdúróṣinṣin  Àwọn àjo oníṣówò àti ẹgbẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ nkàn  pàtàkì  sí Ìṣòwò Ìlú.

Alaga fun igbimọ to n risi  iwa ibajẹ ati awọn ẹsẹ ti o jẹmọ (ICPC), Ojogbon Bolaji Owasanoye sọ eyi di mimọ nibi apejọ itaniji lori iṣe orilẹ-ede ati ilana iṣedeede fun  Awọn Igbimọ alaakoso Iṣowo ati Awọn ẹgbẹ Ọjọgbọn ti o waye ni ilu  Abuja, Naijiria.

Ibaraenisọrọ Sensitization foju jẹ ipilẹṣẹ nipasẹ ICPC ni ifowosowopo pẹlu ọfiisi ti Akọwe si Ijọba Naijiria ati Ile-iṣẹ Iṣalaye Orile-ede (NOA).

ICPC pẹlu ajọṣepọ pẹlu ọfiisi akọwe fun ijọba apapọ ati ile-iṣẹ to n ṣe itaniji fun ara ilu [NOA] ni o ṣe agbekalẹ ibaraẹnisọrọ lori ayelujara ọhun.

Ọga ICPC ṣe akiyesi pe, ikopa ninu iṣẹtọ awọn  ọjọgbọn ati awọn ajọ oniṣowo jẹ pataki julọ gegẹ bii ipa wọn bi awakọ  eto-ọrọ aje orilẹ-ede.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.