Take a fresh look at your lifestyle.

EFCC Gba Mílíónù méérìǹlá-dín-ní-ọ̀tà dín ní ẹgbẹ́rin Fún Àwọn irinṣẹ́ Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti fún Ilé-iṣẹ́ àmújúto

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

158

Ìgbìmọ̀ Aláse  ti fọwọ́sí iye owó tó tó mílíọ́nù mẹ́ẹ́rìǹlá-dín-ní-ọ̀tà dín ní ẹgbẹ̀rin, láti kọ́ ilé àṣẹ àti ìṣàkóso  àti ríra àwọn ohun èlò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ fún ilé iṣẹ́ alátakò náà ní Nàìjíríà,ìyẹn Ìgbìmọ̀ tó ń rísí  Ẹ̀ṣẹ̀ Ìṣòwò àti Owó (EFCC).

Oluranlọwọ pataki fun aarẹ lori ọrọ iroyin ati ipolongo, Garba Shehu, ṣafihan eyi lakoko ti o n ṣe alaye fun awọn oniroyin Ile Ilu, ni opin ipade igbimọ alaṣẹ,ni  Ọjọrú, ti aarẹ Muhammadu Buhari ṣe oludari ẹ.

Agbẹnusọ fun aarẹ naa ṣafikun pe, ifọwọsi naa tun wa lara ifọkansi  pipese eto aabo ati aabo cyber to peye fun EFFC.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.