Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà ṣèlérí láti parí gbogbo àwọn iṣé àṣepatì ní ilẹ̀-ògóni

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

109

Ìjọba Nàìjíríà ṣì dúró lórí  àdéhùn rẹ̀ nípa píparí iṣẹ́ àkànṣe ní ilẹ̀ Ògóni fún ìdàgbàsókè ètò-ọrọ̀ ajé ní agbègbè náà.

Ijọba Naijiria pe akiyesi pe, iṣẹ akanṣe aṣekagba ilẹ ogoni ti ikọ Niger Delta to ju mẹtadin-logun lọni Hydrocarbon Pollution Remediation Project, HYPREP ti ṣe pari .

Minisita fun Ayika Dokita Muhammed Abubakar sọ eyi di mimọ ni ilu Abuja, olu-ilu Naijiria, lakoko apero  kan lori ilọsiwaju ti o ti waye latari aṣepari iṣẹ akanṣe ni ilẹ-ogoni.

Dokita Abubakar ṣalaye pe aṣepari ati awọn iṣẹ miiran ni agbegbe naa yoo tun pese awọn aye iṣẹ ṣiṣe fun awọn eniyan ti eyi yoo si dena ewu  aiṣedeede awọn ọdọ ni agbegbe naa.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.