Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí ń darí àpèjọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

237

Ààre Mùhámmádù Bùhárí ń darí ìpàdé Ìgbìmọ̀ aláṣẹ lórí ayélujára ní yàrá àpèjọ ti ọ́fíísì  Ìyáàfin àkọ́kọ́.

Awọn ti o wa nijoko nibi ipade naa ni, Igbakeji Aarẹ, Yemi Osinbajo, Akowe agba fun Ijọba apapọ, Boss Mustapha ati ọga agba fun Awọn oṣiṣẹ  Aarẹ, Ọjọgbọn Ibrahim Gambari, bakannaa, pẹlu Olori awọn oṣiṣẹ Ilu lapapọ, Folashade Yemi-Esan.

Awọn minisita to tun wa nibẹ bakannaa ni, ti Idajọ, Abubakar Malami, Isuna, Zainab Ahmed,agbara,itaja ati Awọn orisun Omi, Suleiman Adamu.

Awọn yooku ni Babatunde Fashola,Iṣẹ ati ibugbe, Rotimi Amaechi, iṣinipopada ati Dokita Osagie Ehanire,  fun Ilera.

Awọn minisita Miiran  tun n kopa lati  awọn ọfiisi wọn kaakiri ni ilu Abuja.

Wọn bẹrẹ Ipade naa pelu iṣebura fun awọn Akọwe-iduroṣinṣin Titun marun.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.