Take a fresh look at your lifestyle.

Gomina Ìpínlẹ́ Kwara bèèrè ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn ọlọ́jà

Ademọla Adepọju

32

Gomina Ìpínlẹ̀ Kwara, ABDULRAHMAN ADDULRASAQ rọ ìgbìmọ̀ tuntun tí yóò máa darí ìṣòwò ti ilé-isẹ́ tó ń wa kùsà àti ohun ọ̀gbìn (KWACCIMA) ní Ìpínlè kwara kú oríre.

Gomina Abdulrasaq kí àwọn adarí tuntun náà káábọ̀ sí KWACCIMA lábẹ́ akóso Alhaji Olalekan Ayodimeji. Ó sì tún rọ̀ wọ́n pé kí wọ́n jẹ́ òsìsẹ́ takuntakun.

Abdulrazaq sì tún rọ KWACCIMA fún jíjẹ́ ilé-isẹ́ tó sé gbẹ́kẹ̀lé ní gbogbo gba, tí wọ́n sì tún jẹ́ kí ó rọrùn fún ìjọba láti dá ìgbìmọ̀ ìsòwò sílẹ̀.

Ó tún rọ àwọn olùdarí KWACCIMA láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pèlú ̀awọn ọmọ ẹgbé wọn lónà ti ìdàgbàsókè yóò se dé báá ilé-isẹ́.

 

 

 

 

 

 

Hamzat Roshidat

Leave A Reply

Your email address will not be published.