Take a fresh look at your lifestyle.

Ini Edo ṣe ayẹyẹ ogún ọdún tí ó ti bẹ̀rẹ̀ èré orí sinimá

52

Gbajú-gbajà, òsèré orí itage, Ini Edo, ti  ṣe ayẹyẹ ogún ọdún tí ó ti jẹ́ òsèré orí isinima  Nollywood , nígbà tí ó ń fi ìdùnnú rẹ̀ hàn láti  sàlàyé ìgbà tí o ti bẹ̀rẹ̀ eré orí ìtàǵe láti kékeré.

Ini Edo ti o jẹ gbaju -gbaja , ti o si tun ti gba ọpọlopọ ife ẹyẹ gẹgẹ bi osere to dankajia , ni o ti fi idunnu rẹ han lori ẹrọ ayelujara Instagram rẹ  @iniedo   lati kede ogun odun ti o ti bẹrẹ ere ori sinima

Gbaju gbaja Ini Edo bẹrẹ ere ori  sinima ni ọdun  2000, ni eyi ti o ti  darapọ mọ awon akẹgbẹ rẹ lati se eré to le ni Ọgorun un . lọdun 2014, ni ajo agbaye  United Nations yan an agẹgẹ bi asoju rere fun awọn ọ̀dọ́ ni agbaye.

Leave A Reply

Your email address will not be published.