Take a fresh look at your lifestyle.

Gbajú gbajà akọrin Sound Sultan jẹ́ Ọlọ́run nípè, ó kú ní ọmọ odún mẹ́rìnlélógójì

0 111

Gbajú gbajà akọrin olóhùn iyọ̀, Olanrewaju Fasasi ti a mọ si,Sound Sultan jẹ́ Ọlọ́run nípè, ó kú ní ọmọ odún mẹ́rìnlélógójì (44).

Ni owurọ  ọjọ Aiku yii ni awọn ẹbí rẹ̀ kede iku rẹ ninu atẹjade kan ti wọn fi sita.

Olanrewaju Fasasi ti a mọ si,Sound Sultan bẹrẹ orin kikọ ni ọdun 1990.

iyawo ati ọmọ mẹta ni oloogbe naa fi silẹ láyé.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.