Take a fresh look at your lifestyle.

Ìsẹ̀lẹ̀ ìjì tó jà ní orílẹ̀-èdè Gambia pa àwọn ènìyàn mẹwaa

Ademọla Adepọju

92

Lẹ́yìn ìgbà tí ìsẹ̀lẹ̀ ìjì líle náà wáyé mọ́júmọ́ tí ó sì wó àwọn ilé kan ní àwọn agbègbè kọ̀ọ̀kan ní orilẹ̀-ẹdẹ Gambia tí àwọn mẹ́wàá si pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ìsẹ̀lẹ̀ náà.

Ìsẹ̀lẹ̀ ìjì náà ló sàkóbá fún àwọn agbègbe kan tí wọn kò fi ní iná mọ̀nàmọ́ná àti omi ẹ̀rọ ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́bọ̀, léyìn ti àwọn ohun èlò amáyéderùn ti bàjé nipase isele iji nla, ojo ati agbara.

Aare orilẹ-ede Gambia, Adama Barrow seto ipade pajawiri ni ọsan ọjọbọ lati se ayẹwo awọn nnkan to bajẹ ọhun , o si pinnu lati se atunsẹ lori rẹ

 

 

 

 

 

Abdulrafiu Kehinde

Leave A Reply

Your email address will not be published.