Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ fọkàn balẹ̀ kòsí àrùn rọ́mọ lápá-rọ́mọ lẹ́sẹ̀ mọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ademọla Adepọju

0 205

Àjo tó ń mójútó ìdàgbàsókè ilé-ìwòsàn abọ́dé (NPHCDA) ti sọ pé orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti bọ́ lọwọ aarun rọmọ lapa- rọmọ lẹsẹ.

Alásẹ olùdarí NPHCDA, Ọmọwe Faisal Shuaib  ló sọ̀rọ̀ ìdánilójú ọ̀hún nínu ìròyìn tó jáde ní Ìpínlẹ̀ Abuja. Ó tẹnumọ pé láti ìgbà tí wọ́n ti se àyẹ̀wò si tí wọ́n sì ti gba ìwé-ẹ̀rí, ko ti si aarun rọmọ lapa-rọmọ lẹsẹ ni gbogbo ipinlẹ to wa ni orilẹ ede Naijiria.

Adari NPHCDA fi da awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria loju  pe ajọ wọn yoo tẹsiwaju lati maa fọwọsowọpọ pẹlu awọn ti ọrọ kan lati maa polongo abẹrẹ ajẹsara lati dena aarun ọhun.

 

 

 

 

Hamzat Roshidat

Leave A Reply

Your email address will not be published.