Take a fresh look at your lifestyle.

Kì í se ojúse ilé ìgbìmọ̀ asojú-sòfin láti bọwọ́lu àbájáde àtúnse òfìn ètò ìdìbò-Ahmad Lawan

35
Olùdarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà ,Ahmad Lawan,ti ni ki i se ojúse ilé ìgbìmọ̀ asojú-sòfin láti bọwọ́lu àbájáde àtúnse òfìn ètò ìdìbò tí wọ́n sì ń jíròrò lọ́wọ́ nílé ìgbìmọ̀ asòfin tó wà nílùú Àbújá.
Asofin Lawan  sọrọ yii lọjọ Aje lati tako awọn ahesọ ọrọ ti awọn ọmọ orilẹ ede Naijiria kan n gbe jade pe ile igbimọ asofin   fẹ yọ  awọn ọrọ kan kuro , ni eyi ti yoo tako lilo ẹrọ ayelujara lati maa gbe èsì idibo jade  lasiko eto idibo lorilẹ ede Naijiria.
oludari ile igbimọ asofin tun wa tẹnumọ pe  ile igbimọ asofin agba yoo tun se agbeyẹwo abadofin to rọ mọ atunse eto idibo  laarin ọ̀sẹ̀ meji .
Leave A Reply

Your email address will not be published.