Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé ìgbìmọ asòfin Malaysia yóò padà sẹnu isẹ láti se àtúnse òfin

Ademọla Adepọju

31

Ìjọba orílẹ-èdè malaysia ti gbà láti sọ fún àwọn ọba orílẹ-èdè wọn pé ilé ìgbìmò asòfin wọn yóò bèrè isẹ fún ọjọ márún, bẹrẹ láti ọjọ kẹrindínlọgbọn, osù keje sí ọjọ kejì, osù kejọ. alákoso ìjọba Muhyiddin Yassin ló sọ bẹẹ ní ọjọ Ajé.
Muhyiddin tún tẹsíwájú pé, isẹ tí wọn yóò bẹrẹ naa yóò dá lórí, bí wọn yóò se jé kí àwọn nnkan orílẹ-èdè padà sípò, tí àwọn asòfin yóò sí bẹrẹ isẹ lórí àtúnse òfin pàtàkì lati fi darí ìpàdé àwọn ilé ìgbìmọ asòfin ọhun.

Hamzat Roshidat

Leave A Reply

Your email address will not be published.