Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ jẹ kájọ fọwọsowọpọ láti fi òpin sí àrùn Covid-19: Biden

Ademọla Adepọju

53

Ààre orílẹ-èdè America Joe Biden rọ àwon ọmo orílẹ-èdè America láti se ipa ti wọn kán lẹ fi òpin bá àrùn Covid-19 lasiko tí wọn n sí gbọngán ilé ààre, lọjọ Àìkú tí wọn n se ayẹyẹ ọjọ tí orílẹ-èdè wọn pé mẹẹdogun din ni ota le nigba(245).
Ààré Biden se ìdárò àwọn tó pàdánù ẹmí wọn látari ònà àti gbógun ti àrùn Covid-19.
Àmọsá ìjọba Biden ti se ìpinnu pé ayẹyẹ ọdún yìí yóò dá lórí ìyípadà lórí gbígbógunti àkàjálẹ ààrùn , òsì àti pipese àwọn ohun amáyédẹrùn tí yóò se àra ìlú ní ànfààní.
Bó tilẹ jẹ pé àjàkálẹ ààrùn tó sẹlẹ lọdún tó kọjá , ló se ìdíwọ fún ayẹyẹ tó yẹ kí wón see fún un lasiko tí ó jẹ ààrẹ , ní èyí tí ó le aarẹ tẹlẹri Donald Trump kuro nipo gẹgẹ bi aarẹ orilẹ ede America.

Hamzat Roshidat

Leave A Reply

Your email address will not be published.