Take a fresh look at your lifestyle.

COAS – Àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà mú ìṣòkan lọ́kùúnkúndùn láti gbógun ti ikọ̀ ọlọ̀tẹ̀

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

30

Ọ̀gá àgbà fúnilé isẹ  àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà (COAS) ,Ọ̀gágun àgbà Faruk Yahaya àti àwọn ọmọ- ikọ̀ rẹ̀ ,ní Mongadishu Cantonment ní ilé ìjọ́sìn kátólíkì ní Àbújá,  ṣàfihàn àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí àmì  ìṣọ̀kan lónírúurú àti lẹ́nu isẹ́.

Eleyii ni igba  akọkọ ti ọgagun agba fun  ile-isẹ́  ọmọ ogun  ọhun, ti o jẹ Musulumi yoo darapọmọ awọn akẹgbẹ    rẹ ti o jẹ  Kirisitiẹni gẹgẹ bii ayẹyẹ isami ọdun ile-isẹ ọmọ ogun orilẹ ede Naijiria ti ọdun 2021.

COAS tọka si pe ohun n ṣe eyi nitori pe,ohun fẹ ki awọn eniyan mọ pe ologun n ṣiṣẹ gẹgẹ bii ẹyọkan ni.

ọga agba fun ẹka  iṣẹ́ awọn ọmọ ogun,ọgagun agba AB Omozoje,nigbati o n fi imoore ẹ han, dupẹ lọwọ ọlọrun,ọgagun agba,  fun atilẹyin rẹ si  ologun ati si ọga agba fun eto Aabo  ti ọga ajagun Elvis Njoku  ṣe aṣoju rẹ nibi ayẹyẹ naa.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.