Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn ènìyàn mókànlélógún tí wọn sá kúrò lòrìlẹ-èdè wọn ló kú sínú omi ní Tunisia .

Ademọla Adepọju

0 93

Àwọn ènìyàn mókànlélógún ni wọn rí tí wọn ti kú léyìn gbàtí ọkọ ojú omi subú sínú omi Tunisia.

Olùsọ  ojú omi kan sọpé ẹkejì tí irú ìyí yóò selẹ láàrin ọjọ méjì nìyí.

Àwọn tí wọn n sọ ojú omi sí lọ gba àwọn òkú náà padè ní ibùdó Sfax, colonel Houssem jebebi lọjọ Àìkú.

Ní ọjọ Àbámẹta, nígbàtí àwon tí wọn kúrò ní orílẹ-èdè Tunisia gbìyànjú láti sọdà omi Tunisia, àwọn Mẹtalélógún ní wọn rì sínú omi àmọ àwọn olùsọ ojú omi ní ànfàní láti gba ẹmí àwọn mérinlélọgọrin là.

 

 

Hamzat Roshidat

Leave A Reply

Your email address will not be published.